00:00
02:09
(Ayo, Ayo Maff)
(Agree and seek battle)
15 years old mo sa n'le
Owo ni moti'
Owo ni motivation
Mumsy, I no fit dey watch you dey suffer
So, mo ṣe dating
Ah, mo ṣe local
Ṣebi, I no know say music go, go far
The day wey you go meet your helper, your story go change
Ayo Maff, ọmọ owo mi, ṣo da mọ to ba ri?
E no easy, mo tira mi mọ'le fun ọjọ mẹjọ
E no easy, mo tira mi mọ'le fun ọjọ mẹjọ
Ah, iku to pa iya teacher to le pa awọn nigga
F'awọn nigga mi silẹ, I pray we get bigger
Ah, iku to pa iya teacher to le pa awọn nigga
F'awọn nigga mi silẹ, I pray we get bigger
Ah, kaiye ma sọ wa s'okunkun alẹ
Ah, kaiye ma sọ wa s'okunkun ọwọ'
Mo gberin ojo latoke emi ni kan
Mo gberin ojo latoke emi ni kan
Mo woju Oluwa
Mo woju Oluwa
Mo gbadura, mo pray for mercy k'emi ma lọ jabọ
Ko s'ẹni ti mo gbojule, ah, ọwọ rẹ mo wa
Iwọ ṣa lọlọkọ mi, wa mi sibi to da
Obinna, oore to ṣe fun mi lọjọsi
Ẹ wo aye mi lode, orin mi l'ọn jo si
Elijah, Elijah, holy Michael wa loda
Ayo Maff, ẹyọ kan ni, you no fit see another