Account Balance - Mohbad

Account Balance

Mohbad

00:00

02:33

Similar recommendations

Lyric

Account balance lojẹ kí ńma bùga bayi, ah (buga, buga)

Backward, never, naira yàtọ si cefa

Ìmọ́lẹ̀, Zanku, na lamba (Ìmọ́lẹ̀)

(Chech-da-producer)

(Àpá tí jábọ́ o, Jésù)

(Meduaa)

Àpá tí jábọ́ o, Jésù (yebo)

Àwọn kàn lọ f'orí fọ'go

Ẹ wá wo cause trouble yìn o

O tí ko sínú wàhálà t'awa

Àpá tí jábọ́ o, ye o

Àwọn kàn lọ f'orí fọ'go, ye-oh

Ẹ wá wo cause trouble yìn o

O tí ko sínú wàhálà t'awa

Àpá tí jábọ́ o, Jésù

Ń gbọ, kí ló gbé wa s'ori table? (Yeba)

O jà wire, ò ja cable

Ẹní o lówó l'ọwọ, na disable

Gucci o yatọ si bàtá Jésù

Over confidence, ò ma ń jọ àṣeju

Ice lọrun mi, olèkú (olèkú)

Aṣiwaju bi Tinubu

Sunday o dagboru mọ bayi (Sunday o dagboru mọ bayi)

Owó ni Monday mi ń wá bayi (owó ni Monday mi ń wá bayi)

Ọmọ alfa gàn o jí mọ (ọmọ alfa gàn o jí mọ)

Àwọn NEPA gan o ni'na (awọn NEPA gan o ni'na)

Account balance l'ojẹ kí ńma bùga bayi, ah (buga, buga)

Backward, never, naira yàtọ si cefa

Ìmọ́lẹ̀, Zanku, na lamba (kúrò ńbẹ sẹ)

Impossibility, ọta mí o ni borí

Àbí eni l'ẹti ńgbọ l'àdúgbò yín?

Swagu dripping, ọrun blinging

Mo tí l'ọmọ ọpẹ l'àdúgbò yín

Gbàgbé Island, lọ béèrè Mainland

Ja wọ anywere t'oba yọ paper

Ọmọ ale l'oma ko ti'le ta

Fún ẹyín tí ó ye, ò ma ye yín later

Ah, Ìmọ́lẹ̀, k'òkùnkùn bọ'lẹ

Eku níwọn sẹ, wọn ma jẹ sọlẹ̀

Basket no fit fetch water like bucket

I be the plug, sẹ

Sunday o dagboru mọ bayi (Sunday o dagboru mọ)

Owo ni Monday mi ń wá bayi (owó ni Monday mi ń wá bayi)

Ọmọ alfa gàn o jí mọ

Àwọn NEPA gan o ni'na (awọn NEPA gan o ni'na)

Account balance l'ojẹ kí ńma bùga bayi, ah (l'ojẹ kí ńma bùga)

Backward, never, naira yàtọ si cefa

Ìmọ́lẹ̀, Zanku, na lamba (lamba)

One, two, three, o ma fọ (one, two, three, o ma fọ)

Ẹ ní l'oyún l'oma sọ (ẹ ní l'oyún l'oma sọ)

Ẹ ní bi'mọ ọ'ràn l'oma pọn (wallai)

Lamba t'odun, wọn ní lé kọ (wọn ní lé kọ)

Ahn-ahn, a wá o gbọ ń kánkán

Ojú wá o fọ, but a o ri ń kánkán

Pá show Naija, pá show ní London

A tún l'ẹnu, pon-pon-pon

Àpá tí jábọ́ o, Jésù

Àwọn kàn lọ f'orí fọ'go

Ẹ wá wo cause trouble yìn o

O tí ko sínú wàhálà t'awa

Àpá tí jábọ́ o, ye o

Àwọn kàn lọ f'orí fọ'go, ye-oh

Ẹ wá wo cause trouble yìn o

O tí ko sínú wàhálà t'awa

Sunday o dagboru mọ bayi

Owó ni Monday mi ń wá bayi

Ọmọ alfa gàn o jí mọ

Àwọn NEPA gan o ni'na

Account balance l'ojẹ kí ńma bùga bayi, ah

Backward, never, naira yàtọ si cefa

Ìmọ́lẹ̀, Zanku, na lamba (Timi Jay on the track)

- It's already the end -