Casablanca - Shoday

Casablanca

Shoday

00:00

02:43

Song Introduction

There is currently no relevant information available about this song.

Similar recommendations

Lyric

(It's The Billion Boy)

(Kill dem all)

(Ayo, Ayo Maff)

Ṣe lo n pe mi zaddy

Mo ni, "Baby, what is popping?"

Girl, I'm chasing money

Ọrọ owo yẹn ṣa lo ba mi

If I no press you money, that one no mean say I stingy

As ọmọ ọgbọn mo calcu' k'owo ma lọ tan l'ọwọ mi

Casablanca mo wọ sọrun (men, I'm looking fresh and classy)

Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu)

Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi)

One million dollar no do me

(Ọmọ aiye hustle lọ)

Mo ni, "Casablanca mo wọ sọrun" (men, I'm looking fresh and classy)

Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu)

Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi)

One million dollar no do me

(Ọmọ aiye hustle lọ, hustle lọ-ọ-ọ)

Vanilla Bottega

Vanilla Bottega with some Lil Kesh

O le jẹ dollar, o le jẹ naira, a wa ma na owo o

Ibi ire la ma sọ gba si, k'ọmọ owo ko to gba CC

Nothing wey I never see

A f'owo m'ọti le ku s'ode

So, mo fi Azul to'le

Oniyangi ku ro l'ọna mi

Ṣo mọ nnkan to wa l'ọkan mi?

Ah-ah, steeze no go kill me

Valentino l'ori mi

Fendi l'ẹsẹ rẹ

O le ku nitori mi

I blow Hiroshima, Nagasaki

Ba mi ṣẹ dollar, Rasaki

Balenciaga l'ọrun mi

When I dey hustle, ṣo ri mi?

Casablanca mo wọ sọrun (men, I'm looking fresh and classy)

Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu)

Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi)

One million dollar no do me

(Ọmọ aiye hustle lọ)

Mo ni, "Casablanca mo wọ sọrun" (men, I'm looking fresh and classy)

Amiri ṣa mo wọ soju (k'aṣiri ma lọ tu)

Mo ni, "Balenciaga mo wọ s'ẹsẹ (original, no be fugazi)

One million dollar no do me

(Ọmọ aiye hustle lọ, hustle lọ-ọ-ọ)

K'aṣiri ma lọ tu

Original, no be fugazi

(Yo-yo-yours truly, BYLINK Mix)

Ọmọ aiye hustle lọ, hustle lọ-ọ-ọ (kill dem all)

- It's already the end -