Bust Down - Zlatan

Bust Down

Zlatan

00:00

03:16

Song Introduction

**Bust Down** jẹ́ orin tuntun tí Zlatan ti ṣe ìtànkálẹ̀. Orin yìí ń fi ìmọ̀ràn àtàwọn ìtàn ìgbésí ayé Zlatan hàn, pẹ̀lú ìtàn kọ́ńpútà tí ń ru àwọn olùgbọ́ lórí. Pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú àti orin tó ní ìfarapa, “Bust Down” ti jẹ́ kí Zlatan lágbára síi nípa àṣà orin Yorùbá. Orin yìí ti gba àfiyèsí púpò látwọ́ àwọn alákọrin àti àwọn olùgbọ́ ní agbègbè àti káàkiri ilẹ̀ Naijíríà.

Similar recommendations

Lyric

Àdúrà àá gbà oh (ìbílẹ)

Owó yẹn a wa oh (ayii)

Bust down biza-biza lá wá, oh (jẹ kan mọ)

Ọmọ ológo daya oh

(Ob', Obah)

(Kaparichumarimarichopaco)

(What dem-a say?)

Cash money, ọmọ iya mi, jọ (jọ)

Jẹun soke, ọmọ, no dey dull (ko jọ)

Cali Kush yọ eruku, we dey puff

(Puff, puff, pass, my G, ma jẹ tan-n)

Sometimes, me, I pray to the Lord

(Let Thy will be done in my life, o dẹ jọ)

Many, many things I no fit talk

Money fit me, I don't wanna be poor

Ọmọ Iyá mi, ṣàánú mi

Wọn ni koba ẹ, o ní ni injury

E dey gba for my body like skuri

Lagbaja sọ pe ko ni pẹ su mi

Sẹntima mọkan, Sabu-Saburi

Ngba tẹ jẹ ojú mi, ṣé mo wa ku ni?

Mi o le ja boxing, mi oun ṣe Tyson

Won't you pay me? No price me (astala, astala, astala, jẹ o mọ)

Àdúrà àá gbà oh (ah, àdúrà)

Owó yẹn a wa oh (ohh)

Bust down, biza-biza lá wá oh

Ọmọ ológo daya oh (ọmọ ológo 4G)

Àdúrà àá gbà oh (ah, faaji)

Ehh, owó yẹn a wa oh (èèyàn Elon Musk)

Bust down, biza-biza lá wá, oh

Ọmọ ológo daya oh

Kúrò ńbẹ, ah

Ọmọ ológo daya (daya)

Àwọn ọlọtẹ gara, mi o kana (kana)

If e no be Messiah ('siah)

Bawo ni mo ṣe ma gbe half a million dollar saya? (Saya, saya)

Mi o gara, mi o kana

Ǹkan toju mi ri, toju ẹ ba ri, o le mayan (o le wọwi)

If e no be money, apụmaka

Wọn fẹ gbe mi mọ ra, ẹ ma wo barawo bansa (wèrè)

Irú blessing yi kon ṣe fun ọmọ ọlẹ

Poverty bami po mo yọ, igo sẹ, mo yọ ọbẹ

Ṣé lo ń buga tẹlẹ, nísìnyí òun tọrọ ọkẹ

Once beaten twice shy, ọlọgbọn lọlọdẹ

Say, if riches na drug I go take overdose

K'owo yẹn jaburata, kin ma rogún loan

Palmpay agent, no near my zone

Na credit alert I wan dey see for my phone

Àdúrà àá gbà oh

Owó yẹn a wa oh

Bust down, biza-biza lá wá oh

Ọmọ ológo daya oh

Àdúrà àá gbà oh

Ehh, owó yẹn a wa oh

Bust down, biza-biza lá wá oh

Ọmọ ológo daya, oh

Mo ni, "Why tẹ n fọ pe life mi pada be like this?"

Màlúù ti o niru Olúwa lo ń ba le'ṣin (lo ń ba le'ṣin)

Ọmọ wèrè, Olúwa lo ń n ṣọ (lo ń ṣọ)

Àá gbe igba orin, wọn ni ki la fẹ kọ

Ah, moni pe ehn-ehn (gẹn-gẹn)

Loju ọta mi, mo pada di celeb' (ki lo wi?)

Àwọn were, wọn ni mo lọ Cele (ki lo sọ?)

Iku pa diet, moti yọ ẹẹkẹ

Gbọmọ wọ nu Paris, ka lọ jaye Schengen (Espanyol)

Èmi láyé mi, ọlọba, mi o le sẹmpẹ, oh (sẹmpẹ)

Ninu percen' yẹn, mo ma jẹ ń bẹ (mo ma jẹ ń bẹ)

Kẹlẹgbẹ gan má mẹgbẹ o

Kọrọ ẹrin ma pada dọrọ ẹlẹbẹ, oh

Dem say, "Industry na yeba-yebo" (yeba-yebo)

Mo kọ'ti ikún si wọn

Mumsy ni pe kin carry go

Fun wọn ni gbẹdu to dun (gbẹdu to dun)

Gbẹdu to dun bi edikang-ikong ati ẹba igbo

Àdúrà àá gbà oh

Owó yẹn a wa oh

Bust down, biza-biza lá wá oh

Ọmọ ológo daya oh

Àdúrà àá gbà, oh

Ehh, owó yẹn a wa oh

Bust down, biza-biza lá wá oh

Ọmọ ológo daya, oh

Focus, focus

Focus, always on my grind, mo dẹ ń gbadura (ehn-ehn)

Ko dùn, ko pọ, aniṣẹku la ma-ma ni lọ'lá Satira

I no fit talk, I no get stamia

My swag is for foreigner, I want my capital

Mo sare wọ Burj Khalifa, mo dẹ ń pawo now

Next stop, o di Yankee now

- It's already the end -